click below
click below
Normal Size Small Size show me how
Ẹbi Mi
questions/answers
Question | Answer |
---|---|
Ṣé o ní àbúrò? | Rárá, mi ò ní àbúrò |
Ṣé o ní òrẹkunrin? | rara, mo ni orebinrin |
So fo mu ni pa ebi | mo ni baba ati mama. mo ni egbon kan |
kini oruko mama e? | oruko mama mi ni Yuko |
kini oruko baba e? | oruko baba mi ni Jun |
kini oruko egbon e? | oruko egbon mi ni Kotaro. |
kini oruko e? | oruko mi ni Sawa |
se o ni iyawo? | beeni, mo ni iyawo |
kini oruko iyawo e? | oruko iyawo mini Heidi |
omo orile-ede wo ni e? | om orile-ede Amerika ati Japan ni mi |
Nibo ni won bi e si? | Won bi mi si ilu Miyoshi ni ipinle Aichi |
Se o gbo Yoruba? | Mo gbo Yoruba die |
Kini o feran lati Ṣe? | Mo feran lati luwee |
Kini o ko feran lati se? | N ko feran lati gba boolu |
Ise wo ni Baba ń se? | Baba mi je onimo-ero |
Kini baba e feran lati se? | Won feran lati gba goofu |
Kini o máa se ni opin ose? (What will you do at the end of the week) | Mo máa se ise amurele. Mo sì máa sùn (I will do my homework and i will sleep) |
How do you say "I will do my homework" | Mo máa se ise amurele |
How do you say "I will cook" | Mo máa dáná |
Bawo ni a se n soo "I will watch a movie" | Mo máa wo fíìmù |
Bawo ni a se n soo "I will read a book" | Mo máa ka ìwé. |
Bawo ni a se n soo "what do you not like to do" | Kini o ko feran lati se? |
Bawo ni a se n soo "what do you like to do" | Kini mo feran lati se? |
Bawo ni a se n soo "I will go to Indianapolis" | "Mo maa lo si Indianapolis" |